Researchers


“Challenge” Neighborhood – Ibadan

Ibadan: Challenge, a key gateway to the city and a bustling commercial area that has many informal and formal markets, is undergoing urban renewal with many new projects, which have consequently exacerbated spatial inequalities while also turning Challenge into a site of resistance. This neighbourhood provides an opportunity to understand how poor working women move in and out of ‘wealth’ as they negotiate the volatile economy and government attempts to displace the urban poor.

 

Ìbàdàn: Challenge, ọ̀nà kan pàtàkì sí àárín ìgboro àti àgbègbè ibi ìṣekárà-kátà tí ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ibiìtajà ìgbàlódé àti tìbílẹ̀, ti ń gba àyípadà sọ̀gbẹ́dìgboro nípaṣè àwọn iṣẹ́ àkànṣe tuntun, èyí tí ó ti mú kí àìdọ́gba di púpọ̀ tí ó sì tún ń sọ Challenge di ibi tí àwọn ènìyàn ti ń dìde lòdì sí ọrọ̀ ìdájọ́ṣẹ̀gbè.

Àdúgbò yìí fúnni ní àǹfààní láti ní òye ìwọlé sínú àti ìjáde nínú 'ọrọ̀' àwọn obìnrin mẹ̀kúnnù bí wọ́n ti ń dínàádúrà lórí ọ̀rọ̀ ọrọ̀-ajé tí kò dúróore àti ìgbìyànjú ìjọba láti lé àwọn mẹ̀kúnnù tó wà nígboro kúrò.